"Waba wa lo, awa o se o li ore"(Numeri 10:29)
We're Marching to Zion G.H. 395
ENYIN t'e f Oluwa,
E fi ayo nyin han;
E jumo ko orin didun, (2)
Kesi yi' tę naa ka (2)
Egbe: Anyan... Io si Sion';
Sion' t' o darajulo,
Anyan goke lo si Sion'
Ilu Olorun wa.
Je k' awon ni maa ko
Ti ko m' Olorun wa;
Sugbon awa omo Oba (2)
Y'o so ayo wa ka. (2)
Oke Sioni mnu
Egberun adun wa;
Ki a to de gbaungba orun (2)
Pelu ita wura (2)
Nje k' a maa korin lo
K' omije gbogbo gbę,
Anyan ni 'le Emmanuel' (2)
S'aiye didan loke. (2)