"Isun kan yio si sile... fun ese" (Sekariah 13: 1)
Soul Stirring Song 74
MO je omo Olorun, mo we nin' eję Jesu,
Mo nsona, okan mi nfa si 'le loke;.
Lori 'ye ife ngo fo, si ile loke lohun,
Li abo mi, 'lękun y'o si 'le: fun mi.
Egbe: Y'o... si 'lę fun mi...
Y'o... si 'le fun mi...
Nip' eje Odagutan, a ti so mi di mimo,
Halleluyah, 'l ekun Y'o..., si 'le fun mi.
Jesu alabukun fun, f agbara Re di mi mu,
Of apa Re gbe mi, O tu mi ninu,
Emi nsinmi l' aiya Re, Aa!'sinmi naa ti dun to!
Bi ng 'ba d' ohun, 'l ekun Y'o..., si 'le fun mi.
'Lekun Y'o si 'le fun mi, nib' awon 'saaju n'so mi,
Nib' awon asise nsinmi titi lai;
'Gbati 'ji aiye ba tan, a o gba ade iye,
Bawo ni ogo ilu naa y' o ti to!
Jesu y'o tu ewon mi, ngo fo lo 'le mi loke,
Si 'le Baba mi to kun fun ibukun,
Ooro ojo a jiunde, to rin yo gba orun kan
Halleluyah, lekun yo sile fun mi.