"Alejo ati atipo Ii emi" (Genesisi 23:4)
This World is not my Home Praise Book of Songs 111
AIYE kii 'se 'le mi atipo ni mo je,
A to 'sura mi jo si koja 'wosanma;
Awon angel' npe mi lati enu ona,
Ng'ko si tun le ni 'dera ninu aiye mo
Egbe: Oluwa ng 'ko I' ore: t' o dabi Rę,
Bi orun ko ba se 'le mi, kini ngo se?
Awon angel' npe mi lati tenu ona,
Ng 'ko si tun Ie ni 'dera ninu aiye mo.
Eyi ni mo mo pe, gbogbo nwon nreti mi,
Af ese mi ji mi, mo si ntęsiwaiu;
Mo mo pe yio mu ailera nii la a ia,
Ng'ko si tun Ie ni 'dera ninu aiye mo?
Mo ni eni owon ni 'le ogo loke,
Ng 'ko nireti miran, titi ngo fi ri won:
Nwon si nduro de mi lenu bode orun,
Ng 'ko si tun Ie ni 'dera ninu aiye mo?
Ni 'le ogo loke l'a o maa gbe titi;
Awon mimo l' otun l'osi nho fun 'segun
Orin iyin dun nwon gba gbogb' orun kan
Ng 'ko si tun le ni 'dera ninu aiye mo.