"Nwon si so won di funfun ninu eje Odo-aguntan naa" (Ifihan 7:14)
Have You Been to Jesus S.S. S.379
'WO ti to Jesu f' agbara 'wenumo?
Awe nin' ej' Odagutan?
Iwo hangbekele ore-ofe Re?
Awe o nin' ej' Odagutan?
Egbe: Awe O?... nin' eje; ...
Nin'ej' Odagutan fun okan?
Aso re ha funfun? O si mo laulau?
A we o nin' ej' Odagutan?
'Wo mba Olugbala rin lojoojumo?
Awe o nin'ej' Odagutan?
'Wo sinmi le Ẹniti a kan mo 'gi
Awe o nin' ej' Odagutan?
Aso-re funfun lati pad' Oluwa?
O mo lau nin' ej' Odagutan?
Okan re mura fun 'le didan loke?
K'a wę o nin' ej' Odagutan.
Bo ewu eeri-ese si apakan,
K'o si we nin' ej' Odagutan?
Isun kan nsan fun gbogbo okan aimo,
Joo, lo we nin' ej' Odagutan.
No comments:
Post a Comment