"Enikeni ti o ba to Mi wa, Emi ki Yio ta a nu bi o ti wu ki o ri" (Johannu 6:37)
Just as I Am S.S. & S. 473
BI mo ti ri --laisawawi,
Sugbon nitori eje Re,
B'O si ti pe mi pe ki ng wa,
Olugbala, mo de, mo de.
Bi mo ti ri---laiduro pę,
Mo fe k' okan mi mo toto,
Sodo Ret' Ole wę mi mo,
Olugbala, mo de, mo de.
Bi mo ti ri-b' O tilę ję
Ija l'ode, ija ninu;
Eru l'ode, eru ninu,
Olugbala, mo de, mo de.
Bi mo ti ri--- 'osi are,
Mosinwa imularada
Iwo l'Oles" awotan mi,
Olugbala, mo de, mo de.
Bi mo ti ri--'Wo o gba mi,
'Woo gba mi t'owo t'ese,
'Tori mo gba 'leri Rę gbo,
Olugbala, mo de, mo de.
Bi mo ti ri-- ife tire,
L'o sete mi patapata,
Mo di Tire, Tire nikan,
Olugbala, mo de, mo de.
No comments:
Post a Comment