Monday, September 13, 2021

MO FE KIN DABI JESU

 "Ko eko lodo Mi, nitori oninu tutu ati Öniręlę okan li Emi" (Matteu 11:29). 

           H.C.492        C.M.S.48 



MO fe; ki ng daabi Jesu, 

Ninu iwa pele; 

Ko s'eni t'o gboro 'binu 

Lenu Re lękan ri:



Mo fe ki ng dabi Jesu,

L'adura 'gbagbogbo; 

Lori oke ni On nikan 

Lo pade Baba Rẹ.



Mo fe ki ni'dabi Jesu, 

Emi ko ri ka pe, 

Bi nwon ti korira Rę; to, 

Os'enikan ni 'bi.



Mo fe; ki ng daabi Jesu, 

Ninu ise rere; 

K'a le" wi ni pa temi pe, 

"O se 'won t' o le se."



Mo fe ki ni 'dabi Jesu, 

T'o fi 'yonu wi pe, 

"Je k' omode wa sodo Mi" 

Mo fe je ipe Re.



Sugbon ng 'ko dabi Jesu, 

O si han gbaungba bę,

Jesu fun mi l' ore-ofe, 

Se mi ki ng dabi Rę. Amin.

No comments:

Post a Comment

GBA AIYE MI OLUWA

  "Bio se emi ati ile mi ni, Oluwa li awa o maa sin" (Josua 24:15)      Take my Life, and Let it be             G. H. 12 GBA aiye ...